1. AWON ERE (Iseju Mewa)
Piini aso awoleke mo Josefu.
Se atejade awon Olopa Josefu ki o si se atejade aso iwo
leke Josefu ki o si le je ki awon Omo naa kun-un saaju ere
1
Iyan: Download
Yoruba Eko 1Aworan Wiwo |
|
|
Yipada si biboloju ki o si gbiyanju ati mu aso awoleke
alawo si ori Josefu
Iyan: Download
Yoruba Eko 1 Aworan Wiwo
(Ki a fun Omo kookan ni paaki kereyonu kookan ki o
won ma ba pin ati ki o ma ba.)
|
2. ERE EGBE (Iseju Mewa)
ASO ERE: Se patako ilewe mo meji.
Okankan fun egbe mejeeji ya aworan aso iwoleke wa pelu ason
ila. Pin kilaasi naa si egbe meji awon omode yoo sare loye
lati lo to lati lo kun ila kookan pelu maka oloda tabi
kereyonu eyiti o ba wu, ki o si tun sare pada lo odo awon
egbe naa fun elere ti o kan lati sare lo si ibi aso iwoleke
naa. tesiwaju titi ti gbogbo ila naa fi wa ni kikun, egbe
ti o ba ti koko pari ni o jawe olubori.
DOWNLOAD
Yoruba Eko # 1 Aworan Wiwo |
|
|
3. KOROOSI LYIN LARO (Iseju Mewa)
Iyan: Download
'Orin Iyin Yoruba orin' fidio
(pelu itumo geesi)
|
4. IORIN OPE TIMOTIMO: (Iseju Marun)
Iyan: Download
Orin Ope Yoruba fidio
|
|
5. EKO
(a) ATUNYEWO (Iseju Marun)
(Eyi gegebi ikeeko akoko o le ma si atunyewo afi ti eko yii wa siwaju
eko ti o koja)
DOWNLOAD
Yoruba Eko #1 Awon Aranran Wiwo
b. Kiko ese bibeli kan (Iseju Marun-un)
Israeli sì feìràn Josefu ju gbogbo àwon
omo re tókù
lo
Genesisi 37: 3a
DOWNLOAD
Ese Bibeli Yoruba Iranlowo Wiwo
(Gba awon omode na niyanju lati kun-un ati fi ko ese
Bibeli naa) |
|
|
c. Ko Eko naa (Iseju Marundinlogun)
Bible Reading: Genesisi 37: 3-4; 12-13; 17b-24
Optional: Download
Fidio awo iwoleke Josefu
|
DOWNLOAD
'Yoruba Eko
# 1'
Josefu je eya idile kan. Bi o tile je pe Josefu dagba ni
idile ti ko dara, ko je ki awopo ati aibikita ipinle idile
re yi di ona ati sin Olorun lowo. O ko lati fi itan idile
re yi se awawi.
Awa naa je eya idile kan ni aye bee naa ni idile
Ijosin Kristieni. a je aburo Jesu lokunrin ati lobinrin. Ile
ijosin je idile ti a sopo pelu ife fun Olorun baba wa ni orun
ati fun ara wa. |
|
Ni ojo kan Jesu wa pelu awon omo eyin re ni ile kan. Nigbati iya
Jesu ati aburo re de ile naa, won ran enikan lo sinu ile lati lo
wa.
Won so fun Jesu “Iya ati awon aburo re nwa o ni ita”
Jesu wo awon eniyan ti o joko yiika o si dahun wipe “awon
wonyi ni iya ati arakunrin mi! enikeni ti o ba ti n se ife Olorun
ni arakunrin ati arabinrin ati iya mi”.
Se Jesu nife iya ati arakunrin re tooto? Beeni o feran won. Sugbon
o tun mo wipe oun ni
idile miran. O je idile ti o je pe awon ti o nife baba re ti o wa
ni orun ti o si n se ife re.
Emi ati wo nife idile wa, sugbon a tun ni idile igbagbo ti o yanilenu
ti o kun fun awon
arakunrin ati arabinrin ti won feran Olorun ati ti won feran ara
won. O je oun ti o dara lati wa ni ara “idile Olorun”.
http://www.sermons4kids.com
Baba Josefu ti aye feran re, o fun ni ebun ti o yato, se o le ranti
ohun ti iyen je? (O se aso oso fun-un)
Sugbon Josefu tun se iyebiye si Olorun ti o nife re ti o si ma
ko leyin ninu eko yi.
Olorun ko fi sile paapaa julo nigba isoro.
Olorun mo Josefu ki won to bi, o si ni eto nla fun Josefu gegebi
o se nii fun o.
Jeremiah 1:5a "ki o to dip e mo da o lati
inu ni mo ti mo on, ki o to dip e a bi o ni mo ti ya o soto"
Jeremiah 29:11 "Nitori mo mo ero ti mo ro
si yin, ni Oluwa wi, ani ero alaafia, ki I si se fun ibi, ero lati
fun -un yin ni igba ikeyin ati ireti ojo iwaju"
Baba Josefu nife re ju awon arakunrin re lo. Jesu ni ayanfe ati
omo ti baba re nife ju lo.
AKOKO ITAN:
|
Onsotan naa ati Alara 'seraffy'
ere apanilerin ka 'Ati Pippy' Ipin #1 'CoCo
19 ikilo'.
Download
'Ati Pippy' iwe iwaju.
Download
Ipin #1 'Ati Pippy'
Download
Ekunrere iwe itan(To be translated into
Yoruba)
Optional: Download
''Ati Pippy' Awon ese Bibeli
|
Optional: Download
English ‘Joseph coat of many colors’ video
ALAYE AAWO KORONA YORUBA:
Iyan: Download
Yoruba ‘Loye COVID 19’
fidio
Iyan: Download
Yoruba aarun korona ni orilede Naijiria:
wo awon ohun to ye ki o mo nipa ona lati daabo bo ara re lowo
aarun korona. |
|
|
Iyan: Download
‘Fo awon owo re’
iwe paneli oju iwe
Iyan: Download
‘COVID 19' ’iwe paneli
oju iwe
|
ENGLISH CORONA CRISIS INFORMATION:
Optional: Download
‘Fight Coronavirus’ family song
Optional: Download
and view ‘What is Coronavirus and
how to protect yourself’ video
Optional: Download
‘Stay at home stay safe’ video
Optional:Download
‘Wash your hands Healthy Habits’ video
Optional:
Download and sing 'Wash
your hands’ song.
6. OHUN ELO/BIBA OLORUN PADE
Omode kan yoo bere yo si mu, omo miran mo yoo si so pe “DARA
PO MO EBI NA”
won yoo di owo ara won mu ni gbogbo igba, ti won ba ti mu okan ati
pe won yoo
tesiwaju yiyan mo ara won ti won yoo di owo ara won mu titi ti gbogbo
kilaasi yoo fi
di owo ara mu, ti won yoo si maa yin Olorun fun idile re. a ko bi
wa gegebi omo Olorun. o sowa domo nipase Jesu. A o keko nipa bi
a se le di omo Olorun.
ADURA NIPA:
OJU IWE AMURELE/ISE SISE:
Optional:
Download English ‘Activity
Book’
Download
'Yoruba gba ile iranti Bibeli inu ile'
| |
|
OSE TO NBO:
A o keko pe nigbamiran ohun buburu ma nsele
si eniyan rere.
Awon egbon Josefu da le re won si so sinu salanga won si yaa
kuro ni odo baba re. |
Heal a Hurting Heart Curriculum
Just a couple of years ago nearly a quarter of a million
households in Nigeria were at risk after heavy rains caused
flooding that inundated 80 per cent of the country.
|
The rainfall began in July and continued into
September, causing Nigeria’s two main rivers –
the Niger and the Benue – to burst their banks. The
resulting disaster is affecting 34 of the country’s
36 states and has caused 141 deaths and 265 injuries to
date.
CLICK
on the picture link to view our Yoruba flood children's
curriculum.
|
HEAL A HURTING HEART - Corona Crisis
HEAL A HURTING HEART - Natrual Disaster
SOWING SEEDS OF SUCCESS - MORINGA CURRICULUM
|