Project Hope     home >> wowo okan ti o dun mi >> eko 1
Wowo okan ti o dun mi - Eko #1


MO SE PATAKI SI OLORUN-UN

Ni Opin Eko Oye ki Omo naa letii:


• Mo nipa idile Josefu Genesisi 37: 1-4
* Mo pe won je ara ebi kan
* Mo pe baba won ti o wa ni Orun nife
won gidigidi
* Ni imolara pe won se pataki
* Mo pe Olorun da won bi won ti ri ati pe
o ni eto ati ero pataki fun won.

DOWNLOAD 'Yoruba Eko # 1'

BI AWON OMO WEWE SE NDE SAAJU AWON EKO NAA (Iseju Mewa)
Ise Sise (Asayan)
Ki Kilaasi to bere

Da abo bo owo ogbogbo awon Omo naa. rii daju iboju wa ni wiwo, mu orisiriri aso alawo
Onila pamo. Je ki awon omo o lo fun ODE AWO ni agbegbe ibi ti a ti se daradara lati wa
awon Ila aso alawo.

Nigba ti won ba ri awo alawo onila omo naa yoo sare pada wa si patako ajuwe ti o wa ni egbe ogiri yara ikeeko, yoo le aso alawo oni ila mo, patako naa lati se aso iwoleke pelu opolopo awon won/oda.

Awon omo kan le kundun yiya ori ti o ni irugbin ati beebee lo ni ori aso iwo leke naa, nigba ti won ba pari, won yoo ni aworan Josefu titi opin
eto naa.

Iranlowo oju:

  • Ki kilaasi to bere mu orisirisi aso alawo oni ila pamo.
  • Piini ailewu, iwe ti o tobi kan, guluu.
  • Awon kereyannu, te aso Josefu naa jade, ki o si je ki awon Omode naa o kun-un siwaju ere 1
  • Se atejade Olopa Joseph ki o si kun un.
  • Iboju dudu awon asopo atanpako.
  • Se atejade, ese Bibeli fun iranlowo oju ki o si fo awon owo re, posita. Gba awon omo naa lati kun won saaju kilaasi naa.
  • Iwe pelebe, ikowe, pinni asopo, se aso awoleke.
  • Se orun kan pelu aso alawogoolu lori ijoko pelu Jesu ade ati agbelebu onigi, ti a fi aso pupa bo lati ropo eje re se atejade akosori.
  • Ese Bibeli Amurele.
  • Iwe Ise geesi.
  • Awon iwe apere Eko agba atejade Chapter #1 'Ati Pippy'
  • Print English 'A favorite son becomes a slave' colouring pages and Take Home Track
  • Print English 'Keeping children safe during a flood' Adult Educational Handout
  • Print English 'Safety survival tips for a flood' Adult Educational Handout
  • Print English 'Flood Information Sheet' Adult Educational Handout
 
 

1. AWON ERE (Iseju Mewa)
Piini aso awoleke mo Josefu.

Se atejade awon Olopa Josefu ki o si se atejade aso iwo leke Josefu ki o si le je ki awon Omo naa kun-un saaju ere 1

Iyan: Download Yoruba Eko 1Aworan Wiwo

Yipada si biboloju ki o si gbiyanju ati mu aso awoleke alawo si ori Josefu

Iyan: Download Yoruba Eko 1 Aworan Wiwo

 

2. ERE EGBE (Iseju Mewa)
ASO ERE:
Se patako ilewe mo meji.
Okankan fun egbe mejeeji ya aworan aso iwoleke wa pelu ason ila. Pin kilaasi naa si egbe meji awon omode yoo sare loye lati lo to lati lo kun ila kookan pelu maka oloda tabi
kereyonu eyiti o ba wu, ki o si tun sare pada lo odo awon egbe naa fun elere ti o kan lati sare lo si ibi aso iwoleke naa. tesiwaju titi ti gbogbo ila naa fi wa ni kikun, egbe ti o ba ti koko pari ni o jawe olubori.

DOWNLOAD Yoruba Eko # 1 Aworan Wiwo

3. KOROOSI LYIN LARO (Iseju Mewa)

Iyan: Download 'Orin Iyin Yoruba orin' fidio
(pelu itumo geesi)

 

3. ACTIVE ENGLISH PRAISE CHORUS:
(10 minutes)

Optional: Download ‘The family song’ video

Optional: Download 'I am Special' video

 

4. IORIN OPE TIMOTIMO: (Iseju Marun)

Iyan: Download Orin Ope Yoruba fidio

4. INTIMATE ENGLISH WORSHIP: (5 minutes)
Optional: Download 'Our Family under God' video

Optional: Download 'I am special because God has loved me' video and Download lyrics

5. EKO
(a) ATUNYEWO (Iseju Marun)

(Eyi gegebi ikeeko akoko o le ma si atunyewo afi ti eko yii wa siwaju eko ti o koja)

DOWNLOAD Yoruba Eko #1 Awon Aranran Wiwo

 

Optional: Download 'Omo àyànfe jùlo di erú'
Eko # 1 Iwe Itan Iwe Itan Bibeli Yoruba PowerPoint

Gbara lati Bibeli fun Awon omode

 

Iyan: Download 'Omo àyànfe jùlo di erú' Eko # 1 Iwe Itan Iwe Ito Bibeli Yoruba

Gbara lati Bibeli fun Awon omode

 

 

Iyan: Download 'Omo àyànfe jùlo di erú' Eko # 1 Iwe Itan Iwe Ito Bibeli Yoruba PowerPoint

Gbara lati Bibeli fun Awon omode

b. Kiko ese bibeli kan (Iseju Marun-un)
Israeli sì feìràn Josefu ju gbogbo àwon omo re tókù lo
Genesisi 37: 3a

DOWNLOAD Ese Bibeli Yoruba Iranlowo Wiwo

(Gba awon omode na niyanju lati kun-un ati fi ko ese Bibeli naa)

c. Ko Eko naa (Iseju Marundinlogun)

Bible Reading: Genesisi 37: 3-4; 12-13; 17b-24

Optional: Download Fidio awo iwoleke Josefu

DOWNLOAD English 'Yoruba Eko # 1'

Josefu je eya idile kan. Bi o tile je pe Josefu dagba ni idile ti ko dara, ko je ki awopo ati aibikita ipinle idile re yi di ona ati sin Olorun lowo. O ko lati fi itan idile re yi se awawi.

Awa naa je eya idile kan ni aye bee naa ni idile Ijosin Kristieni. a je aburo Jesu lokunrin ati lobinrin. Ile ijosin je idile ti a sopo pelu ife fun Olorun baba wa ni orun ati fun ara wa.

 

Ni ojo kan Jesu wa pelu awon omo eyin re ni ile kan. Nigbati iya Jesu ati aburo re de ile naa, won ran enikan lo sinu ile lati lo wa.

Won so fun Jesu “Iya ati awon aburo re nwa o ni ita”

Jesu wo awon eniyan ti o joko yiika o si dahun wipe “awon wonyi ni iya ati arakunrin mi! enikeni ti o ba ti n se ife Olorun ni arakunrin ati arabinrin ati iya mi”.

Se Jesu nife iya ati arakunrin re tooto? Beeni o feran won. Sugbon o tun mo wipe oun ni
idile miran. O je idile ti o je pe awon ti o nife baba re ti o wa ni orun ti o si n se ife re.

Emi ati wo nife idile wa, sugbon a tun ni idile igbagbo ti o yanilenu ti o kun fun awon
arakunrin ati arabinrin ti won feran Olorun ati ti won feran ara won. O je oun ti o dara lati wa ni ara “idile Olorun”.

http://www.sermons4kids.com

Baba Josefu ti aye feran re, o fun ni ebun ti o yato, se o le ranti ohun ti iyen je? (O se aso oso fun-un)

Sugbon Josefu tun se iyebiye si Olorun ti o nife re ti o si ma ko leyin ninu eko yi.

Olorun ko fi sile paapaa julo nigba isoro.

Olorun mo Josefu ki won to bi, o si ni eto nla fun Josefu gegebi o se nii fun o.

Jeremiah 1:5a "ki o to dip e mo da o lati inu ni mo ti mo on, ki o to dip e a bi o ni mo ti ya o soto"

Jeremiah 29:11 "Nitori mo mo ero ti mo ro si yin, ni Oluwa wi, ani ero alaafia, ki I si se fun ibi, ero lati fun -un yin ni igba ikeyin ati ireti ojo iwaju"

Baba Josefu nife re ju awon arakunrin re lo. Jesu ni ayanfe ati omo ti baba re nife ju lo.

AKOKO ITAN:

Onsotan naa ati Alara 'seraffy' ere apanilerin ka 'Ati Pippy' Ipin #1 'Ikilo ikun omi'.

Download 'Ati Pippy' iwe iwaju.

Download Ipin #1 'Ati Pippy'

Download Ekunrere iwe itan(To be translated into Yoruba)

Optional: Download ''Ati Pippy' Awon ese Bibeli


Iyan: Download ‘Bààlúù Tó N L? ’ fidio

 


Iyan: Download Yoruba 'Igbaradi isan omi' panini awo

ENGLISH FLOOD INFORMATION:

Optional: Download English ‘Flood Preparedness ' Poster

Optional: Download English ‘Disaster Checklist'

 

Optional: Download English 'The Great Storm and Flood Recovery' 32 page colouring book for parents (To translate)


Optional: Download English ‘How to prepare for a flood' video


Optional: Download English ‘Flooding Explanation- Learn about Flood- Video for kids'


Optional: Download English ‘Flood Video for kids'

6. OHUN ELO/BIBA OLORUN PADE

Omode kan yoo bere yo si mu, omo miran mo yoo si so pe “DARA PO MO EBI NA”
won yoo di owo ara won mu ni gbogbo igba, ti won ba ti mu okan ati pe won yoo
tesiwaju yiyan mo ara won ti won yoo di owo ara won mu titi ti gbogbo kilaasi yoo fi
di owo ara mu, ti won yoo si maa yin Olorun fun idile re. a ko bi wa gegebi omo Olorun. o sowa domo nipase Jesu. A o keko nipa bi a se le di omo Olorun.

ADURA NIPA:

OJU IWE AMURELE/ISE SISE:

Optional: Download English ‘Activity Book

Download 'Yoruba gba ile iranti Bibeli inu ile'

 


ENGLISH ADULT EDUCATIONAL HANDOUT:

Optional: Download 'Safety survival tips for a flood' Adult Educational handouts

Optional: Download 'Keeping children safe during a flood' Adult Educational handouts

Optional: Download 'Flood Information Sheet' Adult Educational handouts

OSE TO NBO:

A o keko pe nigbamiran ohun buburu ma nsele si eniyan rere.
Awon egbon Josefu da le re won si so sinu salanga won si yaa kuro ni odo baba re.

 

Heal a Hurting Heart Curriculum

The total number of coronavirus cases in Nigeria have risen to 36,663, bringing the death toll in the country to 789, according to figures from the Nigeria Centre for Disease Control (NCDC) at the end of July.

The hardest-hit states are the commercial capital Lagos with 13,438 infections, the capital Abuja with 3,027 infections, and Oyo with 2,167 infections.

CLICK on the picture link to view our Yoruba COVID 19 children's curriculum.

HEAL A HURTING HEART - NATURAL DISASTER

Efik
Ukrainian
English
French
Portuguese
Chichewa
Dutch
Swahili
Nuer
Twi

HEAL A HURTING HEART - CORONA CRISIS

English
Yoruba
Swahili
French
Portuguese
Malawi
Dutch

SOWING SEEDS OF SUCCESS - MORINGA CURRICULUM

French Lingala
Yoruba
French Creole
English
Swahili
Sowing Seeds of Success Shona
Efik
Nuer
Dutch
Portuguese

SUPER FRUIT CURRICULUM

Dutch
Swahili
English

Chichewa
Nuer

NEW LIFE CURRICULUM

New Life Swahili Child Evangelism Curriculum
New Life Yoruba Child Evangelism Curriculum
New Life Chichewa Child Evangelism Curriculum
New Life French Child Evangelism Curriculum
 
New Life Persian Child Evangelism Curriculum

 
Copyright ©  2024 www.UnitedCaribbean.com. All rights reserved. Disclaimer Click to Contact us
www.unitedcaribbean.com CONTACT (246) 425 1917 MAKE A DONATION